Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì ti tẹjúmọ́ ojú ọ̀run bí ó ti ń lọ sókè, lójijì, àwọn ọkùnrin méjì tí ó wọ aṣọ funfun dúró létí ọ̀dọ̀ wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:1-20