Hósíà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn wọn ń gbóná bí i ààròwọ́n sì tọ̀ ọ́ lọ pẹ̀lú rìkísí,ìbínú wọn pa lọ́lọ́ ní gbogbo òruó sì bú jáde bí ọ̀wọ́ iná ní òwúrọ̀.

Hósíà 7

Hósíà 7:1-14