Hósíà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò kégbe pè mí láti ọkàn wọn,Ṣùgbọ́n wọ́n ń pohùn réré ẹkún lórí ibùsùn wọn.Wọ́n kó ara wọn jọ, nítorí ọkà àti wáìnìṣùgbọ́n wọ́n yípadà kúrò ní ọ̀dọ̀ mi.

Hósíà 7

Hósíà 7:5-16