Hósíà 7:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí èmi ìbá mú Ísírẹ́lì láradá.Ẹ̀ṣẹ̀ Éfúráímù ń farahànìwà búburú Ṣamáríà sì ń hàn sítaWọ́n ń ṣe èrúàwọn olè ń fọ́ iléàwọn ọlọ́ṣà ń jalè ní òpópónà

2. Ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pémo rántí gbogbo ìwà búburú wọn:Ẹ̀ṣẹ̀ wọn gbé wọn mì pátapátawọ́n wà níwájú mi nígbà gbogbo.

3. “Wọ́n ń mú inú ọba dùn pẹ̀lú ìwà búburú wọn,àti inú ọmọ aládé dùn pẹ̀lú irọ́ wọn

Hósíà 7