Hósíà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gílíádì jẹ́ ìlú àwọn ènìyàn búburútí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, a sí ti fi ẹ̀ṣẹ̀ bà á jẹ́.

Hósíà 6

Hósíà 6:1-11