Hósíà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ kí a mọ OlúwaẸ jẹ́ kí a tẹ̀ṣíwájú láti mọ̀ ọ́.Gẹ́gẹ́ bí oòrùn ṣe ń yọ,Yóò jáde;Yóò tọ̀ wá wá bí òjòbí òjò àkọ́rọ̀ ti ń bomirin ilẹ̀.”

Hósíà 6

Hósíà 6:1-9