Hósíà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jẹ́ aláìsòótọ́ sí Olúwawọ́n sì bí àwọn ọmọ àlè.Nísinsìn yìí, ọdún oṣù tuntunwọn, ni yóò pa wọn run pẹ̀lú pín wọn.

Hósíà 5

Hósíà 5:1-15