Hósíà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yìn àlùfáà!Ẹ fetí sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì!Ẹ gbọ́, ẹ̀yìn ilé ọba!Ìdájọ́ yìí kàn yín:Ẹ ti jẹ́ ẹ̀bìtì ní MísípàÀwọ̀n ti a nà sìlẹ̀ lórí Tábórì

Hósíà 5

Hósíà 5:1-11