Hósíà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí èyí, ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀, gbogboolùgbé ibẹ̀ sì ń ṣòfò dànù.Ẹranko igbó àti ẹyẹ ojú ọ̀runàti ẹja inú omi ló ń kú.

Hósíà 4

Hósíà 4:1-7