Hósíà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún àwọn arákùnrin rẹ, ‘Ènìyàn mi,’ kí o sì wí fún àwọn arábìnrin rẹ ‘Àánú.’

Hósíà 2

Hósíà 2:1-7