Hósíà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará Sámáríà gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn,nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí Ọlọ́run wọn.Wọn ó ti ipa idà ṣubú;a ó fọ́ àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀,A ó sì la àwọn aboyún wọn nínú.”

Hósíà 13

Hósíà 13:6-16