Hósíà 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni ọba rẹ gbé wà nìsisin yìí kí ó bá à le gbà ọ là?Níbo ni àwọn olórí ìlú yín wà,àwọn tí ẹ sọ pé,‘Fún wa ní ọba àti ọmọ aládé’?

Hósíà 13

Hósíà 13:6-16