Hósíà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éfúráímù gbéraga,“Èmi ní ìní fún ara mi, mo sì ti di ọlọ́rọ̀,pẹ̀lú gbogbo ọrọ̀ mi yìí, wọn kò le ká àìṣedéédéétàbí ẹ̀ṣẹ̀ kankan mọ́ mi lọ́wọ́”

Hósíà 12

Hósíà 12:6-10