Hósíà 12:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú oyun ni ó ti di arákùnrin rẹ̀ mú ni gìgísẹ̀,àti nípa ìpá rẹ̀ ó ni agbára pẹ̀lú Ọlọ́run

Hósíà 12

Hósíà 12:1-11