Hósíà 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fó okùn ènìyàn fà wọ́nàti ìdè ìfẹ́.Mo mú àjàgà kúrò ni ọrùn wọnMo sì farabalẹ̀ fún wọn ni oúnjẹ.

Hósíà 11

Hósíà 11:1-12