Hósíà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò máa tẹ̀lé Olúwa;òun yóò bú ramúramù bí i kìnnìúnNígbà tó bá búàwọn ọmọ yóò wá ní ìwárìrì láti ìwọ̀ oòrùn.

Hósíà 11

Hósíà 11:9-12