Hósíà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn wọn kún fún ìtànjẹbáyìí wọ́n gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn. Olúwa yóò wó pẹpẹ wọn palẹ̀yóò sì pa gbogbo òkúta ìyàsọ́tọ̀ wọn run.

Hósíà 10

Hósíà 10:1-4