Hósíà 10:14-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. ariwo ogun yóò bo àwọn ènìyàn yínkí gbogbo odi agbára yín ba le parun.Gẹ́gẹ́ bí Ṣalìmanì ṣe pa Bétí-Ábélì run lọ́jọ́ ogun,nígbà tí a gbé àwọn ìyá ṣánlẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn

15. Báyìí ni a o sì ṣe sí ọ, ìwọ Bétélì,nítorí pé ìwà buburú yín ti pọ̀jù.Ní àfẹ̀mọ́júmọ́ ọjọ́ náà,a o pa ọba Ísírẹ́lì run pátapáta.

Hósíà 10