Hágáì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ẹnikẹ́ni bá dé ibi ìlé ogún, mẹ́wàá péré ni. Nígbà tí ẹnikẹ́ni bá dé ibi ìfúntí wáìnì láti wọn àádọ́ta ìwọ̀n, ogún péré ni.

Hágáì 2

Hágáì 2:14-17