Èéṣe tí ìwọ fi mú mi rí àìṣedéédéÈéṣe tí ìwọ sì fààyè gba ìwà ìkà?Ìparun àti ìwà ipá wà ní iwájú mi;ìjà ń bẹ, ìkọlù sì wà pẹ̀lú.