Hábákúkù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú rẹ mọ́ tónítóní láti wo ibi;ìwọ kò le gbà ìwà ìkànítorí kí ni ìwọ ṣe gba àwọn alárékérekè láàyè?Nítorí kí ni ìwọ ṣe dákẹ́ nígbà tí ẹni búburú ń paẹni tí i ṣe olododo ju wọn lọ run?

Hábákúkù 1

Hábákúkù 1:10-17