Hábákúkù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó si máa fí àwọn ọba ṣẹ̀ṣínwọn ó sì tún kẹ́gàn àwọn aládé.Wọn yóò sì fi gbogbo ìlú odi alágbára nì rẹ́rìnín;Nítorí pé, wọn yóò ko erùpẹ̀ jọ, wọn yóò sì gbà á

Hábákúkù 1

Hábákúkù 1:3-17