Gálátíà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àlàáfíà àti àánú wà lórí gbogbo àwọn tí ń rìn ní ìlànà yìí, àti lórí Ísírẹ́lì Ọlọ́run.

Gálátíà 6

Gálátíà 6:9-18