Gálátíà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nínú Kírísítì Jésù ìkọlà kò jẹ́ ohun kan, tàbí àìkọlà; ṣùgbọ́n ìgbàgbọ́ ti ń ṣiṣẹ́ nípa ìfẹ́.

Gálátíà 5

Gálátíà 5:1-11