Gálátíà 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe jẹ́ kí a máa ṣògo-asán, kí a má mú ọmọnìkejì wa bínú, kí a má ṣe ìlara ọmọnìkejì wa.

Gálátíà 5

Gálátíà 5:24-26