Gálátíà 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbọ̀rìṣà, oṣó, ìkórira, ìjà, ìlara, ìbínú, ìmọtara-ẹni nìkan, ìyapa, ẹ̀kọ́-òdí.

Gálátíà 5

Gálátíà 5:19-26