Gálátíà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítorí tí ẹ̀yin jẹ́ ọmọ, Ọlọ́run sì ti rán Ẹ̀mí Ọmọ rẹ̀ wá sínú ọkàn yín, tí ń ké pé, “Ábà, Baba.”

Gálátíà 4

Gálátíà 4:4-15