Gálátíà 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá wù mí láti wà lọ́dọ̀ yín nísinsìnyìí, kí èmi sì yí ohùn mi padà nítorí pé mo dààmú nítorí yín.

Gálátíà 4

Gálátíà 4:10-25