Gálátíà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìbùkún Ábúráhámù ba à lè wá sórí àwọn aláìkọlà nípa Kírísítì Jésù; kí àwa ba à lè gba ìlérí Ẹ̀mí nípa ìgbàgbọ́.

Gálátíà 3

Gálátíà 3:4-19