Gálátíà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òfin kì í sì í ṣe ti ìgbàgbọ́: ṣùgbọ́n “Ẹnikẹ́ni tí ń se wọn yóò yè nípaṣẹ̀ wọn.”

Gálátíà 3

Gálátíà 3:10-13