Gálátíà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Ọlọ́run, ẹni tí ó ṣiṣẹ́ nínú iṣẹ́ ìránsẹ Pétérù gẹ́gẹ́ bí Àpósítélì sí àwọn Júù, òun kan náà ni ó ṣiṣẹ́ nínú iṣẹ́ ìránsẹ mi gẹ́gẹ́ bí Àpósítélì sí àwọn aláìkọlà.

Gálátíà 2

Gálátíà 2:1-12