Gálátíà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò ya oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run sí apákan: nítorí pé bí a bá le ti pasẹ̀ òfin jèrè òdodo, a jẹ́ pé Kírísítì kú lásán.”

Gálátíà 2

Gálátíà 2:19-21