Gálátíà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ọdún mẹ́rìnlá, ni mo tún gòkè lọ sì Jérúsálẹ́mù pẹ̀lú Bánábà, mo sì mú Títù lọ pẹ̀lú mi.

Gálátíà 2

Gálátíà 2:1-5