Gálátíà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bẹ́ẹ̀ ni èmi kò gòkè lọ sì Jerúsálémù tọ àwọn tí í ṣe Àpósítélì ṣáájú mi: ṣùgbọ́n mo lọ sí Árábíà, mo sì tún padà wá sí Dámásíkù.

Gálátíà 1

Gálátíà 1:16-24