Fílípì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa níní ìjàkadì kan náà tí ẹ̀yin ti rí tí èmi là kọjá, ti ẹ sì gbọ́ nísinsinyìí pé mo sì wà nínú rẹ̀.

Fílípì 1

Fílípì 1:23-30