Fílípì 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

láìsí ìbẹ̀rẹ̀ àwọn tí ó dojúkọ yin lọ́nà kanna. Èyí sì jẹ́ àmì fún wọn pé a ó pa wọ́n run, a ó sì gbà yín là —èyí tí Ọlọ́run yí ó ṣe.

Fílípì 1

Fílípì 1:20-30