Fílípì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore-ọ̀fẹ́ sí yín, àti àlàáfíà, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa, àti Olúwa wa Jésù Kírísítì.

Fílípì 1

Fílípì 1:1-7