Fílípì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí mo mọ̀ pé nípa àdúrà yín àti ìrànlọ́wọ́ tí Ẹ̀mí Jésù Kírísítì, ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi yóò padà já sí ìtúsílẹ̀ mi.

Fílípì 1

Fílípì 1:18-23