Fílípì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ti ìkẹ́yìn n fi ìfẹ́ ṣe é, nítorí tí wọ́n mọ̀ pé a ó gbé mi dìde fún ìgbèjà ìyìn rere.

Fílípì 1

Fílípì 1:9-17