Fílípì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹ̀yin kí ó lè dà ohun tí ó dára jùlọ yàtọ̀ mọ̀, kí ẹ sì jẹ́ mímọ́ àti aláìlábàwọ́n títí di ọjọ́ Kírísítì,

Fílípì 1

Fílípì 1:5-19