Fílímónì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìfẹ́ rẹ ti fún mi ní ayọ̀ púpọ̀ àti ìgboyà, nítorí ìwọ, arákùnrin ti tu ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ lara.

Fílímónì 1

Fílímónì 1:1-13