Fílímónì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí bẹ̀ ọ́ nítorí ọmọ mi Ónísímu, ẹni tí ó di ọmọ nígbà tí mo wà nínú ìdè.

Fílímónì 1

Fílímónì 1:1-13