Ẹ́sítà 9:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Módékáì sì kọ ìwé ránsẹ́ sí gbogbo àwọn Júù, sí ìgbéríko mẹ́tadínláàdóje (127) ní ilé ọba Ṣéríṣésì ní ọ̀rọ̀ àlàáfíà àti ìfọ̀kànbalẹ̀

Ẹ́sítà 9

Ẹ́sítà 9:27-32