Ẹ́sítà 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Módékáì ṣe àkọsílẹ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí, ó sì kọ ìwé ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn Júù jákèjádò àgbáyé ọba Ṣéríṣésì, tí ó wà ní tòòsí àti àwọn tí ó wà ní jìnnà réré,

Ẹ́sítà 9

Ẹ́sítà 9:10-26