Ẹ́sítà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba pàṣẹ fún Hámánì pé, “Lọ lẹ́ṣẹ̀ kan náà. Mú aṣọ náà àti ẹṣin kí o sì ṣe gẹ́gẹ́ bí o ṣe sọ fún Módékáì araa Júù, ẹni tí ó jókòó sí ẹnu ọ̀nà ọba. Má ṣe fi ohunkóhun sílẹ̀ nínú ohun tí o ti yàn.”

Ẹ́sítà 6

Ẹ́sítà 6:7-14