Ẹ́sítà 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hámánì tún fi kún-un pé, “Kìí ṣe èyí nìkan. Èmi nìkan ni ayaba Ẹ́sítà pè láti sin ọba wá sí ibi àsè tí ó sè. Bákan náà, ó sì tún ti pè mí pẹ̀lú ọba ní ọ̀la.

Ẹ́sítà 5

Ẹ́sítà 5:8-13