Ẹ́sítà 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Nítorí bí ìwọ bá dákẹ́ ní àkókò yìí, ìrànlọ́wọ́ àti ìtúsílẹ̀ fún àwọn Júù yóò dìde láti ibòmíràn, Ṣùgbọ́n ìwọ àti àwọn ìdílée bàbá à rẹ yóò ṣègbé. Taa ni ó mọ̀ wí pé nítorí irú àkókò yìí ni o ṣe wà ní ipò ayaba?”