Ẹ́sítà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Módékáì gbọ́ gbogbo nǹkan tí ó ṣẹlẹ̀, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀, ó sì fi eérú kunra, ó jáde lọ sí inú ìlú ó kígbe ṣókè ó sì sunkún kíkorò.

Ẹ́sítà 4

Ẹ́sítà 4:1-9