Ẹ́sítà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì se àsè ńlá, àsè Ésítà, fún gbogbo àwọn ọlọ́lá àti àwọn ìjòyè e rẹ̀. Ó sì kéde ìsinmi jákèjádò ìgbéríko ó sì pín ẹ̀bùn fún wọn pẹ̀lú bí ọba ṣe lawọ́ tó.

Ẹ́sítà 2

Ẹ́sítà 2:17-23