Ẹ́sítà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gbogbo ìṣe agbára àti títóbi rẹ̀, papọ̀ pẹ̀lú ìròyìn títóbi Módékáì ní èyí tí ọba ti gbé e ga, kò ha wà nínú àkọsílẹ̀ ìwé ọdọọdún ọba ti Médíà àti ti Páṣíà?

Ẹ́sítà 10

Ẹ́sítà 10:1-3